E se ayewo Ikanni yii
 

IKANSI AKANKAN

È KÀÁBÒ SÍ ORÍ ÈTÒ WÁ ......... ÈKÀ ÈDÈ YORÙBÁ ....

 

Aare Pervez Musharaf ti bura fun olori ijoba tuntun, Yousaf Raza Gulani.

Ogbeni Gilani, eni ti yoo siwaju ijoba tuntun, ti o jeje lati se adinku lilo agbara ipo aare lorile-ede Amerika ati awon akegbe-re.  eni ti o bura ni waju aare Musharaff ni bi ayeye kan ni ilu (Islamabad).

Gilani ti o je alatileyin agba kan fun olori alatako ti won sekupa, Bhutto, ni awon ile – igbimo asofin dibo yan ni ojo aje – Monday, ni ibi ti egbe apapo to n gbogun ti ijoba Musharaff, ti jawe olubori, pelu ero to- po ninu idibo to waye ni osu to – koja.

 

 

Home | Contact | VON | Contact Us | archive
Webmaster@voiceofnigeria.org :Change Password :VON Staff Sign Up
Copyright© 2007. All Rights Reserved Voice Of Nigeria. Developed by: VON ON-LINE

7255KHz 41m; 9690KHz 31m; 11770KHz 25m; 15120KHz  19m