E se ayewo Ikanni yii
 

IKANSI AKANKAN

È KÀÁBÒ SÍ ORÍ ÈTÒ WÁ ......... ÈKÀ ÈDÈ YORÙBÁ ....

 

Ile igbimo Asofin  agba ni orile-ede Pakistan ti pari eto, lati yan olori ijoba tuntun, loni ojo aje-Monday, eyi ti o je ose kaarun ti awon egbe oselu alatako aare Pervez Musharraf jawe oluboei nibi eto idibo gbogboogbo, to waye lorile-ede naa.

Ogbeni Yousaf Raza Gilani, eni ti o je ore timo-timo ologbe Benezir Bhutto ati agbenuso ile- igbimo asofin naa tele-ri, ni iretiwa wipe yi o jawe olubori, ninu eto idibo naa.

 

 

Home | Contact | VON | Contact Us | archive
Webmaster@voiceofnigeria.org :Change Password :VON Staff Sign Up
Copyright© 2007. All Rights Reserved Voice Of Nigeria. Developed by: VON ON-LINE

7255KHz 41m; 9690KHz 31m; 11770KHz 25m; 15120KHz  19m