E se ayewo Ikanni yii
 

IKANSI AKANKAN

È KÀÁBÒ SÍ ORÍ ÈTÒ WÁ ......... ÈKÀ ÈDÈ YORÙBÁ ....

 

Aare tuntun ti won se dibo yan ni orile-ede Taiwan ogbeni Ma Ying-jeou seleri amugberu eto oselu pelu orile-ede China.

Ogbeni Ying-jeou so pe, oun nife lati sies lori adehun alaafia kan pelu orile-ede China, sugbon ki orile-ede China ba ko awon oun ija ogun ti won koju re si oeile-ede Taiwan.

 

 

Home | Contact | VON | Contact Us | archive
Webmaster@voiceofnigeria.org :Change Password :VON Staff Sign Up
Copyright© 2007. All Rights Reserved Voice Of Nigeria. Developed by: VON ON-LINE

7255KHz 41m; 9690KHz 31m; 11770KHz 25m; 15120KHz  19m