O le ni
ogorun-kan (100) eniyan, ti won ti jowo ara-won fun olopaa,
leyin rogbodiyan lati gbogun ti orile-ede China ti o waye ni ilu
Ihasa, lorile-ede Tibet.
Awon
eniyan naa fi ara-won sile, lati sooto, si gbedeke kan, ti awon
alasee fi lele, eyi ti o sope, ijiya yoo wa fun enikeni ti o
kuna lati joowo ara-re.
Awon
ajafeto-omo-eniyan so pe, awon olopaa ilu Lhasa ti lo si
ojuule-si-ojule lati fowo sinkun-mu awon eniyan. Orile-ede
China sope, ifehonu-han naa ko seyin ogbeni Dalai Lama.
Sugbon
Dalai Lama, eni ti o gba ami-eye alafia ni odun 1989, fun
ifara-yingin-re si ifehonu-han alaini-rogbodiyan- ninu, ti
lodi-si oro ti orile-ede China so pe ohun mo nipa rogbodiyan
naa, ni eyi o sip e fun alaafia.
O ti pe
fun, lwadii orile-esde agbaye, lori ohun ti o se okunfa
rogbodiyannaa.
Ifehonu-han naa bere ni ojo kewa osu keta, ni isami iranti , bi
awon omo orile-ede Tibet se gbogun tie to isejoba orile-ede
China, ninu eyi ti o si gboro-sii.