E se ayewo Ikanni yii
 

IKANSI AKANKAN >>> ORILE EDE NAIJIRIA > ILE AFIRIKA > ORILE EDE AGBAYE

È KÀÁBÒ SÍ ORÍ ÈTÒ WÁ ......... ÈKÀ ÈDÈ YORÙBÁ ....

 

 

Aare Boris Tadic ti  Orile ede Serbia tit u ile igbimo asofin orile ede na ka, ti o sip e fun eto idibo lorile ede naa ni ojo kankanla osu kaarun.

Awon minisita naa kuna lati fenuko lori boya ki won jawo ninu ajo isokan ile Europe, lati fi ehonu won han lori igbominira orile ede Kosovo, eyi ti awon omo Ajo ile EU kan nse atileyi re.

 

 

Home | Contact | VON | Contact Us | archive
Webmaster@voiceofnigeria.org :Change Password :VON Staff Sign Up
Copyright© 2007. All Rights Reserved Voice Of Nigeria. Developed by: VON ON-LINE

7255KHz 41m; 9690KHz 31m; 11770KHz 25m; 15120KHz  19m