E se ayewo Ikanni yii
 

IKANSI AKANKAN

È KÀÁBÒ SÍ ORÍ ÈTÒ WÁ ......... ÈKÀ ÈDÈ YORÙBÁ ....

 

KOKO IROYIN:

ILE IGBIMO ASOFIN NI ORILE-EDE NAIJIIRIA BEERE ATUNTO OFIN NI OSU TO N BO. 

WON SE IFILOLE LAGBAYE NI ORILE-EDE NAIJIIRIA LATI SE IGBELARUGE ETO IDAGBASOKE. 

ORILE-EDE COMOROS TI GBA EREKUSU ANJOUAN TI O JE TI AWON OMO OGUN OLOTE. 

AARE ORILE-EDE PAKISTAN BURA FUN OLORI TUNTUN.

E TEETI LEKO O

  • Orin
  • Iroyin
  • Awon eto wa miiran

Awon Eka Ede miran ti e le kan sii...

Awon Eto Wa

Ile igbimo Asofin Agba ni orile-ede naijiiria sope, ohun yoo se agbekale igbimo lori atunto iwe ofin orile-ede Naijiiria ti odun 1999 ni osu ti o nbo.

...... More

Ijoba orile-ede Comoros ti gba isakoso olu-ilu orile-ede naa, ti awon omo ogun olote ni erekusu Anjouan, ni nkan – bi opolopo wakati seyin, leyin atileyin awon omo-ogun Ajo isokan ile-Afirica EU ti won bere..... More

 

 

Aare Pervez Musharaf ti bura fun olori ijoba tuntun, Yousaf Raza Gulani.

Ogbeni Gilani, eni ti yoo siwaju ijoba tuntun, ti o jeje lati se adinku lilo agbara ipo aare lorile-ede Amerika ati awon akegbe-re.......More

 

Home | Contact | VON | Contact Us | archive
Webmaster@voiceofnigeria.org :Change Password :VON Staff Sign Up
Copyright© 2007. All Rights Reserved Voice Of Nigeria. Developed by: VON ON-LINE

7255KHz 41m; 9690KHz 31m; 11770KHz 25m; 15120KHz  19m