E se ayewo Ikanni yii
 

IKANSI AKANKAN

È KÀÁBÒ SÍ ORÍ ÈTÒ WÁ ......... ÈKÀ ÈDÈ YORÙBÁ ....

 

Ile igbimo Asofin Agba ni orile-ede naijiiria sope, ohun yoo se agbekale igbimo lori atunto iwe ofin orile-ede Naijiiria ti odun 1999 ni osu ti o nbo.

Igbakeji Aare ile-igbimo Asofin – agba oloye Ike Ekweremadu siso lori oro yii nigbati o n dahun ibeere lowo awon oniroyin ni ilu Umuahhia, ti o je olu-ilu ipinle Abia.

Osee lalaye pe, ojuse naa nip e, ki oto beere latari ise ti won n se lori iwe abadofin lori isunawo odun 2008 eyi ti o ti wa ni iwaju Aare lati fowosi, bayi.

 

O le ni egberun meedogun awon osise ijoba apapo ti won da duro ni orile-ede Naijiiria ti yoo bere si maa ri eto won gba lati osu to nbo.

Won ti ya owo ti iye re to bilionnu mokandinlogun soto fun sisan owo ajemonu naa, eyi ti yoo kari ile-ise ijoba apapo mokanla.  Osise kan lati ile-ise olusiro owo- agba fun ijoba apapo sofun awon oniroyin ni ilu Abuja pe, idiwo lati san owo naa waye latari iwe akosile ti ko ja gaara lati se akojo iye owo enikookan ninu awon ti oro naakan.

Won da awon osise na duro ni odun ti o koja pelu adehun wipe, won yoo gba sowe-dowo – ajemonu won leyin idanileeko lori eto idase sile ni osu keerin odun ti o koja , April, eyi ti o je odun kan leyin adehun naa, ti won ko – I – ti – san owo ohun.

 

 

Home | Contact | VON | Contact Us | archive
Webmaster@voiceofnigeria.org :Change Password :VON Staff Sign Up
Copyright© 2007. All Rights Reserved Voice Of Nigeria. Developed by: VON ON-LINE

7255KHz 41m; 9690KHz 31m; 11770KHz 25m; 15120KHz  19m