E se ayewo Ikanni yii
 

IKANSI AKANKAN

È KÀÁBÒ SÍ ORÍ ÈTÒ WÁ ......... ÈKÀ ÈDÈ YORÙBÁ ....

 

Won ti ro awon omo orile-ede Naijiirai lati gbiyanju fi owo okunkundun mu awon eto ti yoo mu idagbasoke baa won omode.

Ipe yii waye lati enu agbenuso egbe onigbagbo kan ti o n mojuto awon omode iyen Children Evangelism Ministry , Aarabinrin Emerald Onugbo leyin ipade olojo merin ti awon egbe naa se agbateru r fun odun Ajinde ni ilu Abuja.

Iroyin so pe orisirisi eto bi itan Bibeli, orin iyin adura ati awon ere idaraya miiran ni won ya soto fun awon omode.

Ipade odoodun fun odun Ajinde naa ni won gbe kale lati fi imo olorun to awon omode.  Eto yii waye ni ilu Abuja pelu awon omo-wewe bii egberun merin.

 

Bi won se n sami ojo arun iko jedojedo lagbaye iyen World Tuberculosis Day lati polongo itaniji nipa aisan yii, Ajo ti o n mojuto ilera lagbaye ti a mo sii World Health Organisatio WHO waye pe aisan iko jedo-jedo yii ati Arun HIV ni aisan ti o buru jai ti ko si rorun lati mu kuro nile.

Ajo WHO yii salaye pe aissan iko jedo-jedo yii lo wopo ni opo ibi gbogbo lagbaye, papa julo ni ile- Afirika.

Ajo WHO woye oro yii ninu Abajade eleekejila lori ona ati fopin si aisan iko jedo-jedo lagbaye eyi ti o waye ni odun 2008.

 

 

Home | Contact | VON | Contact Us | archive
Webmaster@voiceofnigeria.org :Change Password :VON Staff Sign Up
Copyright© 2007. All Rights Reserved Voice Of Nigeria. Developed by: VON ON-LINE

7255KHz 41m; 9690KHz 31m; 11770KHz 25m; 15120KHz  19m