E se ayewo Ikanni yii
 

IKANSI AKANKAN

È KÀÁBÒ SÍ ORÍ ÈTÒ WÁ ......... ÈKÀ ÈDÈ YORÙBÁ ....

 

Awon omoleyin kiristenii jake-jado agbaye n sajoyo ojo Eti oloyin lonii, eyi ti I se ojo kan Pataki ninu ayeye odun Ajinde ti won fi kan Jesu mo agbelebu fun igbala awon omo eniyan lori oke-Calvary.

Ni oni ni opo awon omoleyin Kristi maa n wa ninu ile ijosin won lati se iranti ojo ijiya ati iku Jesu pelu awon isin lolokan-o-jokan.

 

Opo awon eniyan ni o n fi idunnu won han si ejo ti igbimo ti o n gbejo eto idibo to koja ni ipinle Edo, eyi won ti kede olori egbe to o n ri si ayedaade awon osise lorile-ede Naijiria tele-ri, ogbeni Adams Oshiomole, gege bi eni ti o jawe olubori ninu eto idibo ipinle naa ti o waye ninu odun to-koja.

Ni ojo-Bo Thursday, ni Aare egbe osise naa bayii; ogbeni Abdul Wahid Ibrahim Omar ti ki eni ti o ipo naa lowo-re, ogbeni Adams Oshiomole ku oriire fun aseyori re nibi igbimo naa.ninu oro-re ti o fi ranse lati orile-ede Geneva ti o ti n se ipade Ajo awon osise lagbaye, Aare egbe osise naaa gege bi igbese petu fun idagbasoke eto oselu tiwa-ntiwa lorile-ede Naijiiria.

 

 

Home | Contact | VON | Contact Us | archive
Webmaster@voiceofnigeria.org :Change Password :VON Staff Sign Up
Copyright© 2007. All Rights Reserved Voice Of Nigeria. Developed by: VON ON-LINE

7255KHz 41m; 9690KHz 31m; 11770KHz 25m; 15120KHz  19m