Ile igbimo
asoju sofin lorile ede Naijiiria ti se apejuwe owo ti o to
billionun merin dola ti agbasese fun ile ise amunawa ti ipinle
Benin ati Asaba gba gege bi eyi ti koye.
Awon omo
ile igbimo naa fie dun okan won han wipe eyi ko boju mu to, ni
iru ipo tie ka ohun elo amusagbare se ri bayi lorile ede
Naijiiria.
Ise akanse
ile ise ina eletiriki ti ilu Benin mo Asaba,ti liu Calaba ni won
gbe fun ile ise Pivot Engineering ninu osu keta odun 2006, pelu
owo ti o to bilionnu maarun dola, ti ireti wa wipe ise naa yoo
pari ninu osu kejila odun 2007.
Oludari
eka ile ise akanse National Independent Power (NIPP), ogbeni
James Olotu jiyan wipe, ida mewa ninu ida ogorun ni won se ninu
ise naa…