E se ayewo Ikanni yii
 

IKANSI AKANKAN >>> ORILE EDE NAIJIRIA > ILE AFIRIKA > ORILE EDE AGBAYE

È KÀÁBÒ SÍ ORÍ ÈTÒ WÁ ......... ÈKÀ ÈDÈ YORÙBÁ ....

 

 

Ile igbimo asoju sofin lorile ede Naijiiria tesiwaju nini gbogbo bi inawo se n lo ni eka ohun elo amusagbara lakoko isakoso eyi ti o koja lorile ede Naijiiria ti ko si mu abajade kan jade, amo omo ile igbimo fie dun okan won han bi ile ise amunawa ti ilu Abuja, eyi ti won se ifilole re ni odun 1999, ko se mu eso rere kan jade. 

Awon omo egbe igbimo naa fi aidunnu won han si oro ti agbenuso fun ile ise amunawa orile ede Naijiiria

(power Holding Company ) Alh. ShuaibuMaigida gbe siwaju won lori ise akanse ile ise amunawa ti ile Abuja naa.

Alaga igbimo naa, ogbeni Ndudi Godwin Elumelu naa fie dun okan re han lori owo ti o ju bilionnu meji ati abo owo dola lo, eyi ti won fifun awon agbaseese ninu owo ti o ju bilionnu meta owo dola ti won se kale fun ise akanse naa, ti o wa ni pamo.

 
 

Home | Contact | VON | Contact Us | archive
Webmaster@voiceofnigeria.org :Change Password :VON Staff Sign Up
Copyright© 2007. All Rights Reserved Voice Of Nigeria. Developed by: VON ON-LINE

7255KHz 41m; 9690KHz 31m; 11770KHz 25m; 15120KHz  19m