E se ayewo Ikanni yii
 

IKANSI AKANKAN

È KÀÁBÒ SÍ ORÍ ÈTÒ WÁ ......... ÈKÀ ÈDÈ YORÙBÁ ....

 

Ijoba orile-ede Comoros ti gba isakoso olu-ilu orile-ede naa, ti awon omo ogun olote ni erekusu Anjouan, ni nkan – bi opolopo wakati seyin, leyin atileyin awon omo-ogun Ajo isokan ile-Afirica EU ti won bere – ise ogun jija lati le ogbeni Muhamed Bacar kuro, eni ti o gba isakoso ninu osu kaarun odun to koja.

Iro ibugbamu ati ibon yinyin naa n waye di owwuro-kutu, ki egbelegbe awon omo ogun na to ya – wo ilu naa pelu ija gege bi ara ikolu olojo-pipe to n waye lati fi gba isakoso. Ko – I si iroyin kankan, boya enikeni fara-pa.

Olori awon omo ogun fun eto aabo, Muhamed Dosara so wipe, awon omo ogun na ti gba olu-ilu Anjouan, eyi ti won ko fibe ja pupo o.

Ogbeni Dosara so wipe, awon omo ogun naa si n waogbeni Bacar, bayii.

 

 

 

Home | Contact | VON | Contact Us | archive
Webmaster@voiceofnigeria.org :Change Password :VON Staff Sign Up
Copyright© 2007. All Rights Reserved Voice Of Nigeria. Developed by: VON ON-LINE

7255KHz 41m; 9690KHz 31m; 11770KHz 25m; 15120KHz  19m