E se ayewo Ikanni yii
 

IKANSI AKANKAN

È KÀÁBÒ SÍ ORÍ ÈTÒ WÁ ......... ÈKÀ ÈDÈ YORÙBÁ ....

 

Olori egbe oselu alatako ni orile-ede Zimbabwe, ogbeni Morgan Tsvangarai so fun awon alatileyin re lati deju- sile tori oju lalakan fi sori, nibi awon ipago idibo ti yoo waye lojo abameta (Saturday )lati dena erongba ijoba aare Mugabe to n wa ona lati es eru ninu eto idibo ohun.

Olori egbe oselu alatako Movement For Democraticc Change (MDC) eyi ti o tobi ju lo ni orile-ede naa, ogbeni Tsvangorai so wipe aare Mugabe ti ji awon eto idibo lati eyin wa, sugbon, o seleri pe, eggbe oselu oun yoo fimu enikeni ti o ba se eru ninu eto idibo ti yoo waye lojo kokandinlogbon osu keta odun ti a wayii danrin.

Aare Mugabe, eni ti o ti wa lori aleefa lati odun mejidinlogbon seyin n koju isoro ti o lagbara julo latodo ogbeni Tsvangirai ati ogbeni Sinba Makoni, eni ti o fi igba kan ri je minisita fun eto isuna owo ni orile-ede naa, eyi ti ipolongo awon mejeeji da loiri fifopin si laasigbo to n salkoba fun eto oro- aje orile-ede naa.

 

 

Home | Contact | VON | Contact Us | archive
Webmaster@voiceofnigeria.org :Change Password :VON Staff Sign Up
Copyright© 2007. All Rights Reserved Voice Of Nigeria. Developed by: VON ON-LINE

7255KHz 41m; 9690KHz 31m; 11770KHz 25m; 15120KHz  19m