E se ayewo Ikanni yii
 

IKANSI AKANKAN

È KÀÁBÒ SÍ ORÍ ÈTÒ WÁ ......... ÈKÀ ÈDÈ YORÙBÁ ....

 

Aare Robert Mugabe ti orile-ede Zimbabwe ti so nibi ipolongo kan ni ilu Harare saaju eto idibo ti yoo waye ni ose to n bop e, ina ni n gba bate lesa adiye, niwon ti oun ba si wa laye ko si egbe oselu alatako kan ti yoo gba aleefa lowo oun.

Alagba omo odun merinlelogoorun naa ni o tun n sapa fun saa eleekerin lori aleefa.  O tun tenu-mo ipinnu-re lati fi oju awon ile-ise Geesi ti o wa ni orile-ede Zimbabwe ri ma – bo, awon ti o n fesun kan pe won n satileyin fun awon egbe alatako.alatako re gboogi ninu eto idibo ohun ni ogbeni Margan Tsvangari ti o je olori egbe oselu Movement for Democracy Change (MDC) ati emewa re kan tele ogbeni Simba Makon.

 

 

Home | Contact | VON | Contact Us | archive
Webmaster@voiceofnigeria.org :Change Password :VON Staff Sign Up
Copyright© 2007. All Rights Reserved Voice Of Nigeria. Developed by: VON ON-LINE

7255KHz 41m; 9690KHz 31m; 11770KHz 25m; 15120KHz  19m