Akowe agba fun ajo isokan orile-ede lagbaye
(United Nation) tele-ri Kofi Annan ti so wipe aheso oro lasan ni
wipe ohun yo ba ise- yiyanju aawo ni agbegbe Darfur lorile-ede
Sudan je.
Egbe alatako kan ni orile-ede Sudan, the Justice
and equality Movement (JEM) ti beere fun ipade ijiroro alaafia
pelu ijoba orile-ede Sudan, won sip e Kofi Annan lati wad a si
oro ohun.
Lakoko ti won n fi oro kan wa ogbeni Kofi Annan
lenu-wo, boya yoo daasi oro naa ni orile-ede Sudan, ogbeni Kofi
annan sope, awon eniyan to poju –osuwon ni won wa ni idi oro naa
ati wipe, ki won fi aye sile fun won lati ma ba ise won lo.