Awon osise
papaako kan ni eti-okun orile-ede Ivory-Coast ti dawon
iyanselodi olose-kan ti o waye latari owo sisan ti o dina kiko
Cocoa ati Kofii wole, duro. Won tun so wipe awon yooo bere
ipade ijiroro pelu olori ijoba orile-ede naaa ati awon
ako-oja-woluu(exporters).
Ogbeni
Fidele Dogba ti o je alaga egbe isokan awon osisse Sytrajop-IC,
ti o se ifilole iyanselodi oun ni ose to- koja, so wipe, awon
osise ajo oun ti pada si enu ise-won bayii. O si so wipe, egbe
osise Sytrajop-IC naa ni won ti bere si n se ijiroro ni ojo
aje-Monday pelu minisita fun awon osise lorile-ede naa.
Ogbeni
Dogba so wipe, won dawo iyanselodi naa duro ki won to tesiwaju
pelu ipade ijiroro naa.
Amo,
iyanselodi ti o waye ni ipari osu kewa si osu keta odun, sokunfa
airi eso-cocoa ko, ni awon papako Pataki kan ti o wa ni ilu
Abijan ati ilu San-pedro ti won je ilu ti o n gbin igi cocoa
julo lagbaye. Awon ako-jato wo ilu (exporters) naa ti so wipe
inu awon ko dun bi awon cocoa awon se n baje..