E se ayewo Ikanni yii
 

IKANSI AKANKAN

È KÀÁBÒ SÍ ORÍ ÈTÒ WÁ ......... ÈKÀ ÈDÈ YORÙBÁ ....

 

Aare Omar al-Bashir ti orile ede Sudan ati aare Idriss Deby ti orile ede Chad ti fowo sii iwe eto adehun alaaafia, ayi ti won se agbekale re lati fi fopin si ikolu awon olote enu ibode nii awon agbegbe kan, eyi ti o wa ni ekun Darfur ti orile ede naa…

Awon orile ede mejeeji ti fenuko lati seto ibasepo to dan moran, ki won si pari aawo ti o wa laarin won.

 

 

Home | Contact | VON | Contact Us | archive
Webmaster@voiceofnigeria.org :Change Password :VON Staff Sign Up
Copyright© 2007. All Rights Reserved Voice Of Nigeria. Developed by: VON ON-LINE

7255KHz 41m; 9690KHz 31m; 11770KHz 25m; 15120KHz  19m