E se ayewo Ikanni yii
 

IKANSI AKANKAN >>> ORILE EDE NAIJIRIA > ILE AFIRIKA > ORILE EDE AGBAYE

È KÀÁBÒ SÍ ORÍ ÈTÒ WÁ ......... ÈKÀ ÈDÈ YORÙBÁ ....

 

 

Orile ede Spain ti yi ipinnu re pada lati daabobo olori egbe oselu alatako orile ede Equatorial Guinea, Severo Moto. 

Ile ejo to gaa julo ni orile ede naa (suprim court) ti fagile ipinnu ijoba lati yo ogbeni Moto, eni ti o sa fi orile ede Guinea sile latari ifipa gba ijoba ni odun 2004, ti o si di asatipo lorile ede Spain.

Ijoba orile ede E-Guinea fesun kan ogbeni Moto pe o kopa ninu ifipa gba ijobanaa, eyi ti o si see esun naa.

Ogbeni Mark Thatcher, eni ti o je omo olori orile ede Britiko tele ri, Magret Thatcher nikan ni o gba wipe oun jebi esun naa.

Ogbeni Mark Thatcher ni won fesun kan ni odun 2005 leyin igba ti o jewo ni orileede South Africa wipe oun se agbateru lai-mo, wipe won fe fi ipa gba ijoba nii.

 

 

Home | Contact | VON | Contact Us | archive
Webmaster@voiceofnigeria.org :Change Password :VON Staff Sign Up
Copyright© 2007. All Rights Reserved Voice Of Nigeria. Developed by: VON ON-LINE

7255KHz 41m; 9690KHz 31m; 11770KHz 25m; 15120KHz  19m